Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Job 1:8 Yorùbá Bibeli (YCE)

Oluwa si sọ fun Satani pe, Iwọ ha kiyesi Jobu iranṣẹ mi, pe, kò si ekeji rẹ̀ li aiye, ọkunrin ti iṣe olõtọ, ti o si duro ṣinṣin, ẹniti o bẹ̀ru Ọlọrun, ti o si korira ìwa buburu.

Ka pipe ipin Job 1

Wo Job 1:8 ni o tọ