Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Job 1:7 Yorùbá Bibeli (YCE)

Oluwa si bi Satani wipe: nibo ni iwọ ti wá? nigbana ni Satani da Oluwa lohùn wipe: ni ilọ siwá sẹhin lori ilẹ aiye, ati ni irinkerindo ninu rẹ̀.

Ka pipe ipin Job 1

Wo Job 1:7 ni o tọ