Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Joṣ 6:21 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nwọn si fi oju idà pa gbogbo ohun ti o wà ni ilu na run, ati ọkunrin ati obinrin, ati ewe ati àgba, ati akọ-mãlu, ati agutan, ati kẹtẹkẹtẹ.

Ka pipe ipin Joṣ 6

Wo Joṣ 6:21 ni o tọ