Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Joṣ 6:20 Yorùbá Bibeli (YCE)

Bẹ̃li awọn enia na hó, nigbati awọn alufa fọn ipè: o si ṣe, nigbati awọn enia gbọ́ iró ipè, ti awọn enia si hó kũ, odi na wólulẹ bẹrẹ, bẹ̃li awọn enia wọ̀ inu ilu na lọ, olukuluku tàra niwaju rẹ̀, nwọn si kó ilu na.

Ka pipe ipin Joṣ 6

Wo Joṣ 6:20 ni o tọ