Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Joṣ 5:9 Yorùbá Bibeli (YCE)

OLUWA si wi fun Joṣua pe, Li oni ni mo yi ẹ̀gan Egipti kuro lori nyin. Nitorina li a ṣe npè orukọ ibẹ̀ ni Gilgali titi o fi di oni yi.

Ka pipe ipin Joṣ 5

Wo Joṣ 5:9 ni o tọ