Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Joṣ 5:10 Yorùbá Bibeli (YCE)

Awọn ọmọ Israeli si dó ni Gilgali; nwọn si ṣe ajọ irekọja li ọjọ́ kẹrinla oṣù li ọjọ́ alẹ, ni pẹtẹlẹ̀ Jeriko.

Ka pipe ipin Joṣ 5

Wo Joṣ 5:10 ni o tọ