Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Joṣ 5:14 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si wipe, Bẹ̃kọ; ṣugbọn bi olori ogun OLUWA ni mo wá si nisisiyi. Joṣua si wolẹ niwaju rẹ̀, o si foribalẹ, o si wi fun pe, Kili oluwa mi ni isọ fun iranṣẹ rẹ̀?

Ka pipe ipin Joṣ 5

Wo Joṣ 5:14 ni o tọ