Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Joṣ 5:13 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si ṣe, nigbati Joṣua wà leti Jeriko, o gbé oju rẹ̀ soke o si wò, si kiyesi i, ọkunrin kan duro niwaju rẹ̀ pẹlu idà fifayọ li ọwọ́ rẹ̀: Joṣua si tọ̀ ọ lọ, o si wi fun u pe, Ti wa ni iwọ nṣe, tabi ti ọtá wa?

Ka pipe ipin Joṣ 5

Wo Joṣ 5:13 ni o tọ