Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Joṣ 4:8 Yorùbá Bibeli (YCE)

Awọn ọmọ Israeli si ṣe gẹgẹ bi Joṣua ti paṣẹ, nwọn si gbé okuta mejila lati inu ãrin Jordani lọ, bi OLUWA ti wi fun Joṣua, gẹgẹ bi iye ẹ̀ya awọn ọmọ Israeli; nwọn si rù wọn kọja pẹlu wọn lọ si ibùsun, nwọn si gbé wọn kalẹ nibẹ̀.

Ka pipe ipin Joṣ 4

Wo Joṣ 4:8 ni o tọ