Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Joṣ 4:7 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbana li ẹnyin o da wọn lohùn pe, Nitori a ke omi Jordani niwaju apoti majẹmu OLUWA; nigbati o rekọja Jordani, a ke omi Jordani kuro: okuta wọnyi yio si jasi iranti fun awọn ọmọ Israeli lailai.

Ka pipe ipin Joṣ 4

Wo Joṣ 4:7 ni o tọ