Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Joṣ 24:17 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitori OLUWA Ọlọrun wa, on li ẹniti o mú wa, ati awọn baba wa gòke lati ilẹ Egipti wá, kuro li oko-ẹrú, ti o si ṣe iṣẹ-iyanu nla wọnni li oju wa, ti o si pa wa mọ́ ni gbogbo ọ̀na ti awa rìn, ati lãrin gbogbo enia ti awa là kọja:

Ka pipe ipin Joṣ 24

Wo Joṣ 24:17 ni o tọ