Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Joṣ 23:5 Yorùbá Bibeli (YCE)

OLUWA Ọlọrun nyin, on ni yio tì wọn jade kuro niwaju nyin, yio si lé wọn kuro li oju nyin; ẹnyin o si ní ilẹ wọn, gẹgẹ bi OLUWA Ọlọrun nyin ti sọ fun nyin.

Ka pipe ipin Joṣ 23

Wo Joṣ 23:5 ni o tọ