Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Joṣ 23:4 Yorùbá Bibeli (YCE)

Wò o, emi ti pín awọn orilẹ-ède wọnyi ti o kù fun nyin, ni ilẹ-iní fun awọn ẹ̀ya nyin, lati Jordani lọ, pẹlu gbogbo awọn orilẹ-ède ti mo ti ke kuro, ani titi dé okun nla ni ìha ìwọ-õrùn.

Ka pipe ipin Joṣ 23

Wo Joṣ 23:4 ni o tọ