Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Joṣ 23:16 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbati ẹnyin ba re majẹmu OLUWA Ọlọrun nyin kọja, ti o palaṣẹ fun nyin, ti ẹ ba si lọ, ti ẹ ba nsìn oriṣa ti ẹnyin ba tẹ̀ ori nyin bà fun wọn; nigbana ni ibinu OLUWA yio rú si nyin, ẹnyin o si ṣegbé kánkan kuro ni ilẹ daradara ti o ti fi fun nyin.

Ka pipe ipin Joṣ 23

Wo Joṣ 23:16 ni o tọ