Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Joṣ 23:15 Yorùbá Bibeli (YCE)

Yio si ṣe, gẹgẹ bi ohun rere gbogbo ti ṣẹ fun nyin, ti OLUWA Ọlọrun nyin ti sọ fun nyin; bẹ̃ni OLUWA yio mú ibi gbogbo bá nyin, titi yio fi pa nyin run kuro ni ilẹ daradara yi ti OLUWA Ọlọrun nyin ti fi fun nyin.

Ka pipe ipin Joṣ 23

Wo Joṣ 23:15 ni o tọ