Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Joṣ 22:11 Yorùbá Bibeli (YCE)

Awọn ọmọ Israeli si gbọ́ pe, Kiyesi i, awọn ọmọ Reubeni, ati awọn ọmọ Gadi, ati àbọ ẹ̀ya Manasse mọ pẹpẹ kan dojukọ ilẹ Kenaani, lẹba Jordani ni ìha keji awọn ọmọ Israeli.

Ka pipe ipin Joṣ 22

Wo Joṣ 22:11 ni o tọ