Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Joṣ 21:44 Yorùbá Bibeli (YCE)

OLUWA si fun wọn ni isimi yiká kiri, gẹgẹ bi gbogbo eyiti o bura fun awọn baba wọn: kò si sí ọkunrin kan ninu gbogbo awọn ọtá wọn ti o duro niwaju wọn; OLUWA fi gbogbo awọn ọtá wọn lé wọn lọwọ.

Ka pipe ipin Joṣ 21

Wo Joṣ 21:44 ni o tọ