Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Joṣ 2:5 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si ṣe li akokò ati tì ilẹkun ẹnubode, nigbati ilẹ ṣú, awọn ọkunrin na si jade lọ: ibi ti awọn ọkunrin na gbé lọ, emi kò mọ̀: ẹ lepa wọn kánkán; nitori ẹnyin o bá wọn.

Ka pipe ipin Joṣ 2

Wo Joṣ 2:5 ni o tọ