Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Joṣ 14:7 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ẹni ogoji ọdún ni mi nigbati Mose iranṣẹ OLUWA rán mi lati Kadeṣi-barnea lọ ṣamí ilẹ na; mo si mú ìhin fun u wá gẹgẹ bi o ti wà li ọkàn mi.

Ka pipe ipin Joṣ 14

Wo Joṣ 14:7 ni o tọ