Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Joṣ 14:6 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbana ni awọn ọmọ Juda wá sọdọ Joṣua ni Gilgali: Kalebu ọmọ Jefunne ti Kenissi si wi fun u pe, Iwọ mọ̀ ohun ti OLUWA wi fun Mose enia Ọlọrun nipa temi tirẹ ni Kadeṣi-barnea.

Ka pipe ipin Joṣ 14

Wo Joṣ 14:6 ni o tọ