Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Joṣ 10:6 Yorùbá Bibeli (YCE)

Awọn ọkunrin Gibeoni si ranṣẹ si Joṣua ni ibudó ni Gilgali, wipe, Má ṣe fà ọwọ́ rẹ sẹhin kuro lọdọ awọn iranṣẹ rẹ; gòke tọ̀ wa wá kánkán, ki o si gbà wa, ki o si ràn wa lọwọ: nitoriti gbogbo awọn ọba Amori ti ngbé ori òke kójọ pọ̀ si wa.

Ka pipe ipin Joṣ 10

Wo Joṣ 10:6 ni o tọ