Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Joṣ 10:5 Yorùbá Bibeli (YCE)

Awọn ọba Amori mararun, ọba Jerusalemu, ọba Hebroni, ọba Jarmutu, ọba Lakiṣi, ati ọba Egloni, kó ara wọn jọ, nwọn si gòke, awọn ati gbogbo ogun wọn, nwọn si dótì Gibeoni, nwọn si fi ìja fun u.

Ka pipe ipin Joṣ 10

Wo Joṣ 10:5 ni o tọ