Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Joṣ 10:37 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nwọn si kó o, nwọn si fi oju idà kọlù u, ati ọba rẹ̀, ati gbogbo ilu rẹ̀, ati gbogbo ọkàn ti o wà ninu rẹ̀; kò kù enikan silẹ, gẹgẹ bi gbogbo eyiti o ṣe si Egloni; o si pa a run patapata, ati gbogbo ọkàn ti o wà ninu rẹ̀.

Ka pipe ipin Joṣ 10

Wo Joṣ 10:37 ni o tọ