Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Joṣ 10:25 Yorùbá Bibeli (YCE)

Joṣua si wi fun wọn pe, Ẹ má ṣe bẹ̀ru, ẹ má si ṣe fòya; ẹ ṣe giri, ki ẹ si mu àiya le: nitoripe bayi li OLUWA yio ṣe si awọn ọtá nyin gbogbo ti ẹnyin mbájà.

Ka pipe ipin Joṣ 10

Wo Joṣ 10:25 ni o tọ