Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jer 9:2 Yorùbá Bibeli (YCE)

A! emi iba ni buka ero ni iju, ki emi ki o le fi enia mi silẹ, ki nlọ kuro lọdọ wọn! nitori gbogbo nwọn ni panṣaga, ajọ alarekereke enia ni nwọn.

Ka pipe ipin Jer 9

Wo Jer 9:2 ni o tọ