Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jer 8:13 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ni kiká emi o ká wọn jọ, li Oluwa wi, eso-àjara kì yio si mọ lori ajara, tabi eso-ọ̀pọtọ lori igi ọ̀pọtọ, ewe rẹ̀ yio si rẹ̀; nitorina ni emi o yàn awọn ti yio kọja lọ lori rẹ̀.

Ka pipe ipin Jer 8

Wo Jer 8:13 ni o tọ