Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jer 7:13 Yorùbá Bibeli (YCE)

Njẹ nisisiyi, nitori ẹnyin ti ṣe gbogbo iṣẹ wọnyi, li Oluwa wi, ti emi si ba nyin sọ̀rọ, ti emi ndide ni kutukutu ti mo si nsọ, ṣugbọn ẹnyin kò gbọ́; ti emi si npè nyin, ṣugbọn ẹnyin kò dahùn.

Ka pipe ipin Jer 7

Wo Jer 7:13 ni o tọ