Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jer 7:12 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ẹ si lọ nisisiyi, si ibujoko mi, ti o wà ni Ṣilo, ni ibi ti emi fi orukọ mi si li àtetekọṣe, ki ẹ si ri ohun ti emi ṣe si i nitori ìwa-buburu enia mi, Israeli.

Ka pipe ipin Jer 7

Wo Jer 7:12 ni o tọ