Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jer 6:26 Yorùbá Bibeli (YCE)

Iwọ, ọmọbinrin enia mi, di ara rẹ ni amure aṣọ-ọ̀fọ ki o si ku ẽru sara, ṣe ọ̀fọ bi ẹniti nṣọ̀fọ fun ọmọ rẹ̀ nikanṣoṣo, pohùnrere kikoro: nitori afiniṣe-ijẹ yio ṣubu lù wa lojiji.

Ka pipe ipin Jer 6

Wo Jer 6:26 ni o tọ