Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jer 50:20 Yorùbá Bibeli (YCE)

Li ọjọ wọnni, ati li akoko na, li Oluwa wi, a o wá aiṣedẽde Israeli kiri, ṣugbọn kì o si mọ́; ati ẹ̀ṣẹ Juda, a kì o si ri wọn: nitori emi o dariji awọn ti mo mu ṣẹkù.

Ka pipe ipin Jer 50

Wo Jer 50:20 ni o tọ