Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jer 50:19 Yorùbá Bibeli (YCE)

Emi o si tun mu Israeli wá si ibugbe rẹ̀, on o si ma bọ ara rẹ̀ lori Karmeli, ati Baṣani, a o si tẹ́ ọkàn rẹ̀ lọrun li oke Efraimu ati ni Gileadi.

Ka pipe ipin Jer 50

Wo Jer 50:19 ni o tọ