Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jer 49:20 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitorina gbọ́ ìmọ Oluwa ti o ti gbà si Edomu; ati èro rẹ̀ ti o ti gba si awọn olugbe Temani pe, Lõtọ awọn ẹniti o kere julọ ninu agbo-ẹran yio wọ́ wọn kiri, lõtọ nwọn o sọ buka wọn di ahoro lori wọn.

Ka pipe ipin Jer 49

Wo Jer 49:20 ni o tọ