Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jer 49:19 Yorùbá Bibeli (YCE)

Wò o, yio goke wá bi kiniun lati igberaga Jordani si ibugbe okuta; nitori lojiji ni emi o lé wọn jade kuro nibẹ, ati tani ayanfẹ na ti emi o yàn sori rẹ̀, nitori tani dabi emi, tani yio si pè mi ṣe ẹlẹri? ati tani oluṣọ-agutan na, ti yio le duro niwaju mi?

Ka pipe ipin Jer 49

Wo Jer 49:19 ni o tọ