Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jer 44:23 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitori ti ẹnyin ti sun turari, ati nitori ti ẹnyin ṣẹ̀ si Oluwa, ti ẹnyin kò gbà ohùn Oluwa gbọ́, ti ẹ kò rin ninu ofin rẹ̀, ati ninu ilana rẹ̀, ati ninu ọ̀rọ ẹri rẹ̀; nitorina ni ibi yi ṣe de si nyin, bi o ti ri li oni yi.

Ka pipe ipin Jer 44

Wo Jer 44:23 ni o tọ