Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jer 44:22 Yorùbá Bibeli (YCE)

Tobẹ̃ ti Oluwa kò le rọju pẹ mọ, nitori buburu iṣe nyin, ati nitori ohun irira ti ẹnyin ti ṣe; bẹ̃ni ilẹ nyin di ahoro, ati iyanu ati ègun, laini olugbe, bi o ti ri li oni yi.

Ka pipe ipin Jer 44

Wo Jer 44:22 ni o tọ