Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jer 44:15 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbana ni gbogbo awọn ọkunrin ti nwọn mọ̀ daju pe, awọn aya wọn ti sun turari fun ọlọrun miran, ati gbogbo awọn obinrin ti o duro nibẹ, apejọ nla, ati gbogbo awọn enia ti ngbe ilẹ Egipti ani ni Patrosi, da Jeremiah lohùn, wipe,

Ka pipe ipin Jer 44

Wo Jer 44:15 ni o tọ