Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jer 44:14 Yorùbá Bibeli (YCE)

Kì o si si ẹniti o sala, ati ẹniti o kù, fun awọn iyokù Juda, ti o wọ ilẹ Egipti lati ma ṣatipo nibẹ, ti yio pada si ilẹ Juda, si eyiti nwọn ni ifẹ ati pada lọ igbe ibẹ: nitori kò si ọkan ti yio pada bikoṣe iru awọn ti o sala.

Ka pipe ipin Jer 44

Wo Jer 44:14 ni o tọ