Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jer 42:2 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nwọn si sọ fun Jeremiah woli, pe, Awa bẹ ọ, jẹ ki ẹ̀bẹ wa ki o wá siwaju rẹ, ki o si gbadura fun wa si Oluwa Ọlọrun rẹ, ani fun gbogbo iyokù yi; (nitori lati inu ọ̀pọlọpọ, diẹ li awa kù, gẹgẹ bi oju rẹ ti ri wa:)

Ka pipe ipin Jer 42

Wo Jer 42:2 ni o tọ