Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jer 42:17 Yorùbá Bibeli (YCE)

Bẹ̃ni gbogbo awọn ọkunrin ti nwọn gbe oju wọn si ati lọ si Egipti lati ṣatipo nibẹ; nwọn o kú, nipa idà, nipa ìyan, tabi nipa àjakalẹ-arun, ẹnikẹni ninu wọn kì yio kù, tabi kì o sala kuro ninu ibi ti emi o mu wá sori wọn.

Ka pipe ipin Jer 42

Wo Jer 42:17 ni o tọ