Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jer 37:21 Yorùbá Bibeli (YCE)

Sedekiah, ọba, si paṣẹ pe ki nwọn ki o fi Jeremiah pamọ sinu agbala ile-túbu, ati pe ki nwọn ki o ma fun u ni iṣu akara kọ̃kan lojojumọ, lati ita awọn alakara, titi gbogbo akara fi tan ni ilu. Jeremiah si wà li agbala ile-túbu.

Ka pipe ipin Jer 37

Wo Jer 37:21 ni o tọ