Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jer 35:17 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitorina bayi li Oluwa Ọlọrun Israeli wi pe, Wò o, emi o mu wá sori Juda, ati sori gbogbo olugbe Jerusalemu, gbogbo ibi ti emi ti sọ si wọn; nitori ti emi ti ba wọn sọ̀rọ, nwọn kò si gbọ́; mo si ti pè wọn, nwọn kò si dahùn.

Ka pipe ipin Jer 35

Wo Jer 35:17 ni o tọ