Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jer 29:23 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitori nwọn ti hùwa wère ni Israeli, nwọn si ba aya aladugbo wọn ṣe panṣaga, nwọn si ti sọ̀rọ eke li orukọ mi, ti emi kò ti pa li aṣẹ fun wọn: emi tilẹ mọ̀, emi si li ẹlẹri, li Oluwa wi.

Ka pipe ipin Jer 29

Wo Jer 29:23 ni o tọ