Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jer 29:22 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ati lati ọdọ wọn li a o da ọ̀rọ-egún kan silẹ li ẹnu gbogbo igbekun Juda ti o wà ni Babeli, wipe; Ki Oluwa ki o ṣe ọ bi Sedekiah, ati bi Ahabu, awọn ẹniti ọba Babeli sun ninu iná.

Ka pipe ipin Jer 29

Wo Jer 29:22 ni o tọ