Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jer 23:33 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ati nigbati awọn enia yi, tabi woli, tabi alufa, yio bi ọ lere wipe, kini Ọ̀rọ-wuwo Oluwa? nigbana ni iwọ o wi fun wọn Ọ̀rọ-wuwo ni eyi pé: Emi o tì nyin jade, li Oluwa wi.

Ka pipe ipin Jer 23

Wo Jer 23:33 ni o tọ