Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jer 20:9 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitorina mo si wipe, emi kì yio mu ni ranti rẹ̀, emi kì yio si sọ ọ̀rọ li orukọ rẹ̀ mọ́. Ṣugbọn ọ̀rọ rẹ̀ mbẹ bi iná ti njó ninu mi ti a se mọ inu egungun mi, o si rẹ̀ mi lati pa a mọra, emi kò le ṣe e.

Ka pipe ipin Jer 20

Wo Jer 20:9 ni o tọ