Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jer 20:10 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitoriti mo gbọ́ ẹgan ọ̀pọlọpọ, idãmu niha gbogbo, nwọn wipe: fi sùn, awa o si fi sùn. Gbogbo awọn ọrẹ mi, ati gbogbo awọn ẹgbẹ mi wipe: bọya a o tãn jẹ, awa o si ṣẹgun rẹ̀, a o si gbẹsan wa lara rẹ̀.

Ka pipe ipin Jer 20

Wo Jer 20:10 ni o tọ