Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jer 20:7 Yorùbá Bibeli (YCE)

Oluwa, iwọ ti fi ọ̀rọ rọ̀ mi, emi si gba rirọ̀! iwọ li agbara jù mi lọ, o si bori mi; emi di ẹni iyọ-ṣuti-si lojojumọ, gbogbo wọn ni ngàn mi!

Ka pipe ipin Jer 20

Wo Jer 20:7 ni o tọ