Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jer 20:5 Yorùbá Bibeli (YCE)

Pẹlupẹlu emi o fi ọrọ̀ ilu yi, pẹlu ẽre rẹ̀ ati ohun iyebiye rẹ̀, ati gbogbo iṣura awọn ọba Juda li emi o fi le ọwọ awọn ọta wọn, ti yio jẹ wọn ti yio si mu wọn lọ si Babeli.

Ka pipe ipin Jer 20

Wo Jer 20:5 ni o tọ