Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jer 20:4 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitori bayi li Oluwa wi, sa wò o, emi o fi ọ le idãmu lọwọ, pẹlu gbogbo awọn ọrẹ rẹ, nwọn o ṣubu nipa idà awọn ọta wọn, oju rẹ yio si ri i, emi o si fi gbogbo Juda le ọwọ ọba Babeli, on o si mu wọn lọ ni igbèkun si Babeli, yio si fi idà pa wọn.

Ka pipe ipin Jer 20

Wo Jer 20:4 ni o tọ