Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jer 16:11 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbana ni iwọ o wi fun wọn pe, Nitoripe awọn baba nyin ti kọ̀ mi silẹ, li Oluwa wi, ti nwọn si rìn tọ̀ ọlọrun miran lọ, ti nwọn si sìn wọn, ti nwọn si foribalẹ fun wọn, ti nwọn kọ̀ mi silẹ, ti nwọn kò pa ofin mi mọ;

Ka pipe ipin Jer 16

Wo Jer 16:11 ni o tọ